Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati onidajọ na ba kú, nwọn a si pada, nwọn a si bà ara wọn jẹ́ jù awọn baba wọn lọ, ni titọ̀ ọlọrun miran lẹhin lati ma sìn wọn, ati lati ma fi ori balẹ fun wọn; nwọn kò dẹkun iṣe wọn, ati ìwa-agidi wọn.

Ka pipe ipin A. Oni 2

Wo A. Oni 2:19 ni o tọ