Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 18:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si kọ si awọn ọmọ Dani. Nwọn si yi oju wọn pada, nwọn wi fun Mika pe, Kili o ṣe ọ, ti iwọ fi kó irú ẹgbẹ bẹ̃ lẹhin wá?

Ka pipe ipin A. Oni 18

Wo A. Oni 18:23 ni o tọ