Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 16:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn ijoye Filistini kó ara wọn jọ lati ru ẹbọ nla kan si Dagoni oriṣa wọn, ati lati yọ̀: nitoriti nwọn wipe, Oriṣa wa fi Samsoni ọtá wa lé wa lọwọ.

Ka pipe ipin A. Oni 16

Wo A. Oni 16:23 ni o tọ