Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 13:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn on sọ fun mi pe, Kiyesi i, iwọ o lóyun, iwọ o si bi ọmọkunrin kan; nitorina má ṣe mu ọti-waini tabi ọti lile, bẹ̃ni ki o má ṣe jẹ ohun aimọ́ kan: nitori Nasiri Ọlọrun li ọmọ na o jẹ́ lati inu wá titi di ọjọ́ ikú rẹ̀.

Ka pipe ipin A. Oni 13

Wo A. Oni 13:7 ni o tọ