Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 12:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN ọkunrin Efraimu si kó ara wọn jọ, nwọn si kọja si ìha ariwa; nwọn si wi fun Jefta pe, Ẽṣe ti iwọ fi rekọja lati bá awọn ọmọ Ammoni jà, ti iwọ kò si pè wa ki awa ki o le bá ọ lọ? awa o fi iná kun ile rẹ mọ́ ọ lori.

Ka pipe ipin A. Oni 12

Wo A. Oni 12:1 ni o tọ