Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 11:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jefta si wi fun awọn àgba Gileadi pe, Bi ẹnyin ba mú mi pada lati bá awọn ọmọ Ammoni jà, ti OLUWA ba si fi wọn fun mi, emi o ha jẹ́ olori nyin bi?

Ka pipe ipin A. Oni 11

Wo A. Oni 11:9 ni o tọ