Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 10:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia na, awọn olori Gileadi si wi fun ara wọn pe, ọkunrin wo ni yio bẹ̀rẹsi bá awọn ọmọ Ammoni jà? on na ni yio ṣe olori gbogbo awọn ara Gileadi.

Ka pipe ipin A. Oni 10

Wo A. Oni 10:18 ni o tọ