Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Titu 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

kì í ṣe nítorí iṣẹ́ rere kan tí a ṣe, ṣugbọn nítorí àánú rẹ̀ ni ó fi gbà wá là, nípa ìwẹ̀mọ́ pẹlu omi tí ó fi tún wa bí, ati Ẹ̀mí Mímọ́ tí ó fi sọ wá di ẹni titun.

Ka pipe ipin Titu 3

Wo Titu 3:5 ni o tọ