Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Titu 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí gbolohun ẹnu rẹ jẹ́ ti ọmọlúwàbí, tí ẹnìkan kò ní lè fi bá ọ wí. Èyí yóo mú ìtìjú bá ẹni tí ó bá fẹ́ ṣe alátakò nígbà tí kò bá rí ohun burúkú kan sọ nípa wa.

Ka pipe ipin Titu 2

Wo Titu 2:8 ni o tọ