Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Titu 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹni tí ó fi ara rẹ̀ fún wa, láti rà wá pada kúrò ninu gbogbo agbára ẹ̀ṣẹ̀, ati láti wẹ̀ wá mọ́ láti fi wá ṣe ẹni tirẹ̀ tí yóo máa làkàkà láti ṣe iṣẹ́ rere.

Ka pipe ipin Titu 2

Wo Titu 2:14 ni o tọ