Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Titu 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí tí mo ṣe fi ọ́ sílẹ̀ ní Kirete ni pé kí o ṣe àtúnṣe àwọn ohun tí ó kù tí kò dára tó, kí o sì yan àwọn àgbà lórí ìjọ ní gbogbo ìlú, gẹ́gẹ́ bí mo ti ṣe ìlànà fún ọ.

Ka pipe ipin Titu 1

Wo Titu 1:5 ni o tọ