Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Titu 1:12-13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkan ninu wọn tí ó jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn wolii wọn sọ pé, “Òpùrọ́ paraku ni àwọn ará Kirete, ẹhànnà, ẹranko, ọ̀lẹ, alájẹkì.” Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ yìí. Nítorí náà má gbojú fún wọn, bá wọn wí kí wọ́n lè ní igbagbọ tí ó pé.

Ka pipe ipin Titu 1

Wo Titu 1:12-13 ni o tọ