Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa ja ìjà rere ti igbagbọ. Di ìyè ainipẹkun mú. Ohun tí Ọlọrun pè ọ́ fún nìyí, òun sì ni ẹ̀rí rere tí o fi ẹnu ara rẹ jẹ́ níwájú ọpọlọpọ ẹlẹ́rìí.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 6

Wo Timoti Kinni 6:12 ni o tọ