Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé nígbà tí wọn bá ń tọ ojúlé kiri, wọ́n ń kọ́ láti ṣe ìmẹ́lẹ́. Kì í sì í ṣe ìmẹ́lẹ́ nìkan, wọn a máa di olófòófó ati alátojúbọ̀ ọ̀ràn-ọlọ́ràn, wọn a sì máa sọ ohun tí kò yẹ.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 5

Wo Timoti Kinni 5:13 ni o tọ