Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

tí a jẹ́rìí sí iṣẹ́ rere rẹ̀, tí ó tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ dáradára, tí ó máa ń ṣe eniyan lálejò, tí kò sí iṣẹ́ tí ó kéré jù tí kò lè ṣe fún àwọn onigbagbọ, tí ó ti ran àwọn tí ó wà ninu ìyọnu lọ́wọ́. Ní kúkúrú, kí ó jẹ́ ẹni tí ń ṣe iṣẹ́ rere nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 5

Wo Timoti Kinni 5:10 ni o tọ