Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Má máa fi ohùn líle bá àwọn àgbàlagbà wí, ṣugbọn máa gbà wọ́n níyànjú bíi baba rẹ. Máa ṣe sí àwọn ọdọmọkunrin bí ẹ̀gbọ́n ati àbúrò rẹ.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 5

Wo Timoti Kinni 5:1 ni o tọ