Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa ṣọ́ ara rẹ ati ẹ̀kọ́ rẹ. Dúró ṣinṣin ninu wọn. Tí o bá ń ṣe bẹ́ẹ̀, ìwọ yóo gba ara rẹ là ati àwọn tí ó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 4

Wo Timoti Kinni 4:16 ni o tọ