Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Janesi ati Jamberesi ti tako Mose, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọkunrin wọnyi tako òtítọ́. Orí irú àwọn eniyan bẹ́ẹ̀ ti kú, a sì ti ṣá wọn tì ní ti igbagbọ.

Ka pipe ipin Timoti Keji 3

Wo Timoti Keji 3:8 ni o tọ