Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí àwọn eniyan yóo wà tí ó jẹ́ pé ara wọn ati owó nìkan ni wọn óo fẹ́ràn. Wọn óo jẹ́ oníhàlẹ̀, onigbeeraga, ati onísọkúsọ. Wọn yóo máa ṣe àfojúdi sí àwọn òbí wọn. Wọn óo jẹ́ aláìmoore; aláìbọ̀wọ̀ fún Ọlọrun,

Ka pipe ipin Timoti Keji 3

Wo Timoti Keji 3:2 ni o tọ