Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ranti Jesu Kristi tí a jí dìde kúrò ninu òkú, tí a bí ninu ìdílé Dafidi. Ìyìn rere tí mò ń waasu nìyí.

Ka pipe ipin Timoti Keji 2

Wo Timoti Keji 2:8 ni o tọ