Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun ti fi ìpìlẹ̀ yìí lélẹ̀, tí ó dúró gbọningbọnin. Àkọlé tí a kọ sára èdìdì tí ó wà lára rẹ̀ nìyí: “Ọlọrun mọ àwọn ẹni tirẹ̀,” ati pé, “Gbogbo àwọn tí ó bá ń pe orúkọ Oluwa níláti kúrò ninu ibi.”

Ka pipe ipin Timoti Keji 2

Wo Timoti Keji 2:19 ni o tọ