Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

tí ó gbà wá là, tí ó pè wá láti ya ìgbé-ayé wa sọ́tọ̀. Kì í ṣe pé ìwà wa ni ó dára tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi pè wá. Ṣugbọn ó pè wá gẹ́gẹ́ bí ètò tí òun fúnrarẹ̀ ti ṣe, ati nípa oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ tí ó fi fún wa nípasẹ̀ Kristi Jesu láti ayérayé.

Ka pipe ipin Timoti Keji 1

Wo Timoti Keji 1:9 ni o tọ