Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 1:17-18 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Nígbà tí ó dé Romu, ó fi ìtara wá mi kàn, ó sì rí mi.

18. Kí Oluwa jẹ́ kí ó lè rí àánú rẹ̀ gbà ní ọjọ́ ńlá náà. Iṣẹ́ iranṣẹ tí ó ṣe ní Efesu kò ṣe àjèjì sí ìwọ alára.

Ka pipe ipin Timoti Keji 1