Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 1:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Èmi Paulu, aposteli Kristi Jesu, nípa ìfẹ́ Ọlọrun gẹ́gẹ́ bí ìlérí ìyè tí ó wà ninu Kristi Jesu, èmi ni mò ń kọ ìwé yìí–

2. Sí Timoti, àyànfẹ́ ọmọ mi.Kí oore-ọ̀fẹ́, àánú ati alaafia láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun Baba, ati Kristi Jesu, Oluwa wa, wà pẹlu rẹ.

Ka pipe ipin Timoti Keji 1