Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ rí i pé ẹnikẹ́ni kò fi burúkú gbẹ̀san burúkú lára ẹnikẹ́ni. Ṣugbọn nígbà gbogbo kí ẹ máa lépa nǹkan rere láàrin ara yín ati láàrin gbogbo eniyan.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 5

Wo Tẹsalonika Kinni 5:15 ni o tọ