Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, kò nílò pé a tún ń kọ̀wé si yín mọ́ nípa ti àkókò ati ìgbà tí Oluwa yóo farahàn.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 5

Wo Tẹsalonika Kinni 5:1 ni o tọ