Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí kò ní jẹ́ kí ẹnikẹ́ni fi ojú tẹmbẹlu arakunrin rẹ̀, tabi kí ó ṣẹ arakunrin rẹ̀ nípa ọ̀ràn yìí. Nítorí ẹlẹ́san ni Oluwa ninu àwọn ọ̀ràn wọnyi, gẹ́gẹ́ bí a ti sọ fun yín tẹ́lẹ̀, tí a wá tún ń kìlọ̀ fun yín nisinsinyii.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:6 ni o tọ