Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, ní ìparí ọ̀rọ̀ mi, a fi Jesu Oluwa bẹ̀ yín, a sì rọ̀ yín pé gẹ́gẹ́ bí ẹ ti gba ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀ wa ní ọ̀nà tí ó yẹ, kí ẹ máa rìn bí ó ti wu Ọlọrun. Bí ẹ ti ń ṣe ni kí ẹ túbọ̀ máa ṣe.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:1 ni o tọ