Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nisinsinyii, Timoti ti ti ọ̀dọ̀ yín dé, ó ti fún wa ní ìròyìn rere nípa igbagbọ ati ìfẹ́ yín. Ó ní ẹ̀ ń ranti wa sí rere nígbà gbogbo, ati pé bí ọkàn yin ti ń fà wá, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn ti àwa náà ń fà yín.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 3

Wo Tẹsalonika Kinni 3:6 ni o tọ