Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Oluwa fi agbára fun yín, kí ọkàn yín lè wà ní ipò mímọ́, láìní àléébù, níwájú Ọlọrun Baba wa nígbà tí Oluwa wa Jesu bá farahàn pẹlu gbogbo àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 3

Wo Tẹsalonika Kinni 3:13 ni o tọ