Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwa náà ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun nígbà gbogbo, nítorí nígbà tí ẹ gba ọ̀rọ̀ Ọlọrun tí ẹ gbọ́ lẹ́nu wa, ẹ gbà á bí ó ti rí gan-an ni. Bí ọ̀rọ̀ Ọlọrun ni ẹ gbà á, kì í ṣe bí ọ̀rọ̀ eniyan. Ọ̀rọ̀ náà sì ń ṣiṣẹ́ ninu ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 2

Wo Tẹsalonika Kinni 2:13 ni o tọ