Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu adura wa sí Ọlọrun Baba wa, à ń ranti bí igbagbọ yín ti ń mú kí ẹ ṣiṣẹ́, tí ìfẹ́ yín ń jẹ́ kí ẹ ṣe akitiyan, tí ìrètí tí ẹ ní ninu Oluwa wa Jesu Kristi sì ń mú kí ẹ ní ìfaradà.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 1

Wo Tẹsalonika Kinni 1:3 ni o tọ