Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni pé, kì í ṣe àwọn ọmọ tí a bí nípa ti ara lásán ni ọmọ Ọlọrun. Àwọn ọmọ tí a bí nípa ìlérí Ọlọrun ni a kà sí ìran Abrahamu.

Ka pipe ipin Romu 9

Wo Romu 9:8 ni o tọ