Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ta ni ọ́, ìwọ ọmọ-eniyan, tí o fi ń gbó Ọlọrun lẹ́nu? Ǹjẹ́ ìkòkò lè wí fún ẹni tí ó ń mọ ọ́n pé, “Kí ló dé tí o fi ṣe mí báyìí?”

Ka pipe ipin Romu 9

Wo Romu 9:20 ni o tọ