Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Òtítọ́ ni ohun tí mò ń sọ yìí; n kò purọ́, nítorí Kristi ni ó ni mí. Ọkàn mi tí Ẹ̀mí ń darí sì jẹ́ mi lẹ́rìí pẹlu, pé,

Ka pipe ipin Romu 9

Wo Romu 9:1 ni o tọ