Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí àwọn tí ń lépa nǹkan ti ẹran-ara nìkan fi jẹ́ ọ̀tá Ọlọrun, nítorí àwọn ẹni bẹ́ẹ̀ kò lè fara wọn sábẹ́ àṣẹ Ọlọrun; wọn kò tilẹ̀ lè ṣe é rárá ni.

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:7 ni o tọ