Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà, Ẹ̀mí tún ń ràn wá lọ́wọ́ ninu àìlera wa. Nítorí a kò mọ ohun tí ó tọ́ tí à bá máa gbadura fún. Ṣugbọn Ẹ̀mí fúnrarẹ̀ a máa bẹ̀bẹ̀ fún wa lọ́dọ̀ Ọlọrun lọ́nà tí a kò lè fi ẹnu sọ.

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:26 ni o tọ