Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ti ìrètí yìí ni a fi gbà wá là. Ṣebí ohun tí a bá ti fojú rí ti kúrò ní ohun tí à ń retí. Àbí, ta ni í tún máa ń retí ohun tí ó bá ti rí?

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:24 ni o tọ