Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wàyí ò, tí a bá jẹ́ ọmọ, ajogún ni wá. Tí a bá sì jẹ́ ajogún, a jẹ́ pé àwa pẹlu Kristi ni a óo jọ jogún pọ̀, bí a bá bá Kristi jìyà, a óo bá a gba iyì pẹlu.

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:17 ni o tọ