Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí tí Ọlọrun fun yín kì í ṣe èyí tí yóo tún sọ yín di ẹrú, tí yóo sì máa mu yín bẹ̀rù. Ṣugbọn Ẹ̀mí tí ó sọ yín di ọmọ ni ẹ gbà. Ẹ̀mí yìí náà ni ó jẹ́ kí á lè máa ké pe Ọlọrun pé, “Baba! Baba wa!”

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:15 ni o tọ