Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí Kristi bá ń gbé inú yín, bí ara yín yóo tilẹ̀ kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀, sibẹ ẹ̀mí yín yóo wà láàyè nítorí pé Ọlọrun ti da yín láre.

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:10 ni o tọ