Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí mo ti wòye, àwọn ẹ̀yà ara mi ń tọ ọ̀nà mìíràn, tí ó lòdì sí ọ̀nà tí ọkàn mi fẹ́, ọ̀nà òdì yìí ni ó gbé mi sinu ìgbèkùn ẹ̀ṣẹ̀ tí ń bẹ ninu àwọn ẹ̀yà ara mi.

Ka pipe ipin Romu 7

Wo Romu 7:23 ni o tọ