Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwà mi kò yé èmi alára; nítorí kì í ṣe àwọn nǹkan tí mo bá fẹ́ ṣe ni mò ń ṣe, àwọn nǹkan tí mo kórìíra gan-an ni mò ń ṣe.

Ka pipe ipin Romu 7

Wo Romu 7:15 ni o tọ