Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpẹ́ ni fỌlọrun, nítorí pé ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ṣẹrú ẹ̀ṣẹ̀ tẹ́lẹ̀ rí, ti wá ń fi tọkàntọkàn gba irú ẹ̀kọ́ tí a gbé kalẹ̀ níwájú yín.

Ka pipe ipin Romu 6

Wo Romu 6:17 ni o tọ