Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó bá lè kú fún wa nígbà tí a sì jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀, nisinsinyii tí Ọlọrun ti dá wa láre nítorí ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, yóo fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn ju ti àtẹ̀yìnwá lọ, a óo sì torí rẹ̀ gbà wá kúrò ninu ibinu tí ń bọ̀.

Ka pipe ipin Romu 5

Wo Romu 5:9 ni o tọ