Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, bí òfin tí ẹnìkan rú ṣe ti gbogbo ọmọ aráyé sinu ìdájọ́ ikú, bẹ́ẹ̀ náà ni iṣẹ́ rere ẹnìkan yóo yọ gbogbo ọmọ aráyé ninu ìdájọ́ ikú sí ìyè.

Ka pipe ipin Romu 5

Wo Romu 5:18 ni o tọ