Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe bẹ́ẹ̀ nìkan, ṣugbọn à ń yọ̀ ninu Ọlọrun nítorí ohun tí ó ṣe nípa Oluwa wa Jesu Kristi, ẹni tí ó sọ wá di ọ̀rẹ́ Ọlọrun ní àkókò yìí.

Ka pipe ipin Romu 5

Wo Romu 5:11 ni o tọ