Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ni kí á rí dìmú ninu ọ̀rọ̀ yìí? Ṣé àwa Juu sàn ju àwọn orílẹ̀-èdè yòókù lọ ni? Rárá o! Nítorí a ti wí ṣáájú pé ati Juu ati Giriki, gbogbo wọn ni ó wà ní ìkáwọ́ ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Romu 3

Wo Romu 3:9 ni o tọ