Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 2:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn láti jẹ́ Juu tòótọ́ jẹ́ ohun àtinúwá; ìkọlà jẹ́ nǹkan ti ọkàn. Nǹkan ti ẹ̀mí ni, kì í ṣe ti inú ìwé. Ìyìn irú ẹni bẹ́ẹ̀ wà lọ́dọ̀ Ọlọrun, kì í ṣe ọ̀dọ̀ eniyan.

Ka pipe ipin Romu 2

Wo Romu 2:29 ni o tọ