Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn tí kì í ṣe Juu tí kò mọ Òfin bá ń ṣe ohun tí Òfin sọ bí nǹkan àmútọ̀runwá, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn kò mọ Òfin, wọ́n di òfin fún ara wọn.

Ka pipe ipin Romu 2

Wo Romu 2:14 ni o tọ